Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ó lé ní ogójì ọdún tí mo ti ní àrùn ìtọ̀ súgà – Ebenezer Obey
LÁGBO ÀRÍYÁ - February 26, 2017

Ó lé ní ogójì ọdún tí mo ti ní àrùn ìtọ̀ súgà – Ebenezer Obey

O tun salaye idi ti ko fi fe’yawo miiran leyin iku aya re, Juliana

 

Baba Miliki, Oloye Ebenezer Obey, to se alaye idi re ti ko fi fe iyawo miiran leyin odun kesan-an ti iyawo, Ojise Olorun Juliana,  re di oloogbe.

O ni ife ti awon ni si ara awon ati bi obinrin naa se fe oun lo fa a .

Gege bi Obey, eni ti yoo pe eni odun marundinlogorin (75 years) ninu osu kerin odun yii, se so, o ni nigba ti oun ati Juliana koko pade, oun nifee si i gidi.

Juliana naa nifee si Obey, sugbon awon eniyan ko fe ki o fe okunrin naa tori won gba pe awon olorin ko ni laari.

Akorin naa wa ni ife ti Juliana ni si oun, ati bi o se ba oun jiya nigba ti nnkan ko tii dara tobee fun oun lo fa a ti oun ko fi fe elomiiran nigba ti o ku.

Obey tun so pe Olorun Oba ni alaabo oun, to si da emi oun si.

O ni lati igba ti oun ti je omo ogbon odun ni oun ti ni ito suga, ti awon oyinbo n pe ni diabetes, sugbon pelu isora, igboran si awon dokita lenu ati ogo Olorun, oun naa niyi lonii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…