Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ìsubú Claudio Ranieri: Nínú eré bọ́ọ̀lù, àgbọ̀nrín èsín kò seé jẹ lọ́bẹ̀.
ERÉ ÌDÁRAYÁ - February 26, 2017

Ìsubú Claudio Ranieri: Nínú eré bọ́ọ̀lù, àgbọ̀nrín èsín kò seé jẹ lọ́bẹ̀.

Otito oro gbaa nip e ninu ere boolu, agbonrin esin ko see je lobe

Idi niyi ti awon agbaboolu fi fe maa n fie mi ara won se ise naa, tori owo kekere ko ni awon to gba won sise n san fun won.

Sugbon awon ti adanwo wa lori won ju ni awon koosi ti a mo si adari awon egbe agbaboolu naa.

Bi won ko ba ti se daadaa, awon to ni egbe agbaboolu won kii wo o leemeji ti won fi maa n begi fun won.

Won ki sii fe wo o pe eni kan se daadaa lesin-in, ki won fi ori aisedeede ti odun yii jin in.

Dipo bee, won a gba a nipako jade ni.

Eyi lo sese sele si Claudio Raniery, eni to se bebe lodun to koja, nigba ti o gba ami eye EPL League fun Licester  United, eyi to wa ni kilaasi keji (Division 2) tele.

Gbogbo eniyan lo n gbe e bi oba niwoyi esin, ti awon to ni egbe agbaboolu naa n ke e loju ati imu.

Sugbon lose to lo, bi eni yo jiga ni won yo o, eyi ti opo awon ololufe re ko dunnu si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…