Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Ìdí tí a gbọdọ̀ fi gbàdúrà fún Buhari – T. B. Joshua
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - February 26, 2017

Ìdí tí a gbọdọ̀ fi gbàdúrà fún Buhari – T. B. Joshua

Oludasile ijo Synagogue Church of All Nations, Pasito T. B. Jshua, ti ke si gbogbo omo Naijiria pe ki won ma dake adura lori Aare Muhammadu Buhari.

T.B. Joshua so lasiko to n waasu ni soosi re to wa ni Ikotun, ni Ipinle Eko, pe ohun to ye ko je koko lokan awon omo Naijiria bayii ni ilera Aare orile-ede yii tori ko si eni ti ko le se aisan. A  ko si mo eni to le ra lola.

O se alaye pe erongba Buhari lori Naijiria dara pupo, to si je pe o nilo ilera lati le se bi okan re se ri.

O ro awon omo Naijiria pe ki won si gba adura ki eto ijoba ara wa le so eso rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…