Home LÁGBO ÀRÍYÁ Àwo tí mo se fún Awolowo ní 1979 ló gbé mi jáde – Lanrewaju Adepọju
LÁGBO ÀRÍYÁ - February 26, 2017

Àwo tí mo se fún Awolowo ní 1979 ló gbé mi jáde – Lanrewaju Adepọju

Ogbontarigi akewi, Olanrewaju Adepoju, ti se alaye idagbasoke re lri ise ewi kike ati iyipada lori aye re.

Okunrin ti ewi re maa n gbona gege bii ariwo Sango naa so pe oun ko lo si sukuu kankan ri, ti oun ko si ni satifikeeti kankan.

Sibesibe, o di eni to n ba olowo, olola ati awon omowe rin.

Lanrewaju sise oniroyin ri ni awon ile ise telifisan kan ni Ibadan.

O so pe igba ti oyinbo siso wu oun ni oun bere sii kawe funra oun.

O ni owo igi ti oun n se ta ni abule awon to wa ni eba Akufo, ni agbegbe Ibadan, ni oun fi maa n ra iwe.

Lanrewaju Adeposu so pe ibagbepo oun ati awon obi oun ni abule oko lo fun un loye lati maa kewi.

O wa so pe awo orin to gbe oun jade ju ni eyi ti oun se fun Oloye Obafemi Awolowo ni odun 1979, nigba ti idibo Second Republic n bo.

O ni atile atoko ni won ti gba awo naa.

O tun ranti pe awo ‘Iku Awolowo’, ti odikeji re je ‘Nibo la n Lo?’ naa ta daadaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…