Home iroyin CODE LAGOS: Ijoba Eko fe fun eniyan milionu kan ni asiri komputa
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - February 23, 2017

CODE LAGOS: Ijoba Eko fe fun eniyan milionu kan ni asiri komputa

Awon eniyan bii milionu kan ni won yoo je anfaani imo asiri komputa, ninu eto pataki kan ti ijoba Ogbeni Akinwunmi Ambode sese fe bere.
Eto naa ni ijoba Eko fe fi fun awon omo ile iwe ati odo langba miiran ni kokoro komputa, ti yoo wule fun idagbasoke ilu.
Eto naa ni won pe ni CODE LAGOS.
Gege bi Olubadamoran Agba fun Gomina Ambode lori Eto Eko, Ogbeni Olafela Bank-Olemo, se salaye, ijoba yoo sise po pelu awon onimo ijinle ninu sayensi komputa.
Won yoo se eto eko fun awon eniyan ni awon ibudo kaakiri yara ikawe ati awon sukuu kan.
Bank-Olemo ni eto yii yo tubo mu idagbasoke ba oro aje tori awon ti yoo maa sise ni awon ile ise yoo tubo jafafa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…