Madam àti Jọkẹ́ (ọmọ ọ̀dọ̀)
Madam àti Jọkẹ́ (Ọmọ ọ̀dọ̀)
Madam – Joke ! kin lo de ti o gbe aga si ibi?
Joke – Awon oga lo ni ki n ba awon mu nnkan loke
Madam – Haa! Ode ni e, pata re loga n woo
Joke – Mi o mo ooo
Madam – Oo gbodo dan iru re wo mo
Joke – O daa ma.
Madam – (Ni ojo miran) Joke kin lo tun de to fi gbe aga si ibi peluu bi mo se kilo fun e to?
Joke – Awon oga ni won tun ni ki n ba awon mu nnkan loke.
Madam – Haaa! Iwo omo yii, o o ni oro gbo. (madam n naa)
Joke – E ma binu ma, n o wo nnkankan lote yii ki oga ma baa tun maa wo pata mi.
Madam – Haaaaa! Joke pa mi ooooo ….
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…