EFE
Okunrin kan lo pe ileese Radio ni ilu Ibadan, o ni oun ri Milionu mewaa naira ti o le je ti ogbeni Donald James, plot 4, Diamond Estate, Ibadan. Osise ileese naa ni o kare laye gege bi omo Naijiria rere. Won wa ni igba wo lo maa gbe owo naa wa si ileese radio, ki olowo le wa gba ni odo awon.
Arakunrin naa ni, ni igba ti ori oun ko daru, ni asiko Buhari ni ohun maa ri Milionu mewaa he ti oun si maa daa pada. O ni idi ti oun fi pe won ni lati ba oun lo orin – my helper ooo, my helper ooo lori radio won …
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…