Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ó wá yé Guardiola báyìí pé “àtàrí àjànàkú ni EPL”
ERÉ ÌDÁRAYÁ - February 19, 2017

Ó wá yé Guardiola báyìí pé “àtàrí àjànàkú ni EPL”

Nigba ti adari egbe agbaboolu Man City n bo lati Germany, nibi to ti se adari awon Bayern, ohun to wa lokan re ni pe oun yoo fi oju awon akegbe re ri mabo.
O gbagbo pe pelu awon agba oje agbaboolu to wa ni Man City, ati iriri oun ni Bayern pelu Barcelona, bi eni feran jeko ni oun yoo se maa lu awon eniyan.
Sugbon bayii, okere EPL ti fe gori iroko, oju ode Guardiola fe da.
Nje Man City si le yi kadara ara re pada lodun yii mo?
O digba naa na, ka to gbomo oba f’osun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…