Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Modu Sheriff di eegun ẹja sí PDP lọ́rùn, Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní òun ni alága!
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - February 18, 2017

Modu Sheriff di eegun ẹja sí PDP lọ́rùn, Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní òun ni alága!

Iru wahala to n sele si egbe PDP latigba ti APC ti foju re gbole ninu idibo odun to lo, eni kan ko gbodo maa gbadura ki o maa sele ninu ile oun o.
Eyi to le ju ni ti eni to ye ko je olori egbe naa, ti o ti wa di isu ata yan-an yan-an.
Nigba ti awon omo egbe ti won pe ara won ni ojulowo, eyi ti Ahmed Mkarfi je olori fun, sese bere sii ma yo pe ogun Modu Sheriff ti se, igba naa ni ile ejo kotemilorun kan ni ipinle Rivers da ejo lojo Jimoo to lo pe okunrin naa ni alaga fun egbe.
Pelu bi oro se wa ri yii, iyan tun ti di atungun, ti obe si ti di atunse.
Awon kan ni iromi to n jo leti omo ni oro Modu naa, pe onilu re n be ninu igbo.
Won ni o jo pe egbe APC lo n sise fun, ko le da maa da PDP ru.
Sugbon, eyi o wu ka wi lori oro to wa nile yii, ti ile ejo ni ase.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…