Home ỌRỌ̀-AJÉ FCMB gbé mọ́tò fún oníbárà rẹ̀
ỌRỌ̀-AJÉ - February 18, 2017

FCMB gbé mọ́tò fún oníbárà rẹ̀

Inu arakunrin kan, Samuel Precious, dun de gongo ni ojo Falentain to lo nigba ti banki ti a mo si First City Monument Bank (FCMB) gbe moto tuntun kan fun un.
Eyi ni ebun ti Samuel je nibi ipolongo kan ti banki naa se, lati dun awon onibara re niu.
Awon omo ileewe miiran je ebun owo iranlowo fun eto eko, eyi ti a mo si bursary.
Idije naa wa fun awon to ba si a-ka-n-ti ti #FlexxWithFCMB, nibi ti o gbodo ti maa ni owo ti o to egberun mewaa naira nigbogbo igba.
Nibi asekagba idije naa to waye ni osibitu LUTH, ni Idi Araba, ni ilu Eko, Samuel gba moto Hyundai tuntun, ti ogorun eniyan miiran si je ebun foonu.
Gbogbo won ni won dupe lowo awon alase ile ifowopamo naa.
Enikeni to ba wa fe kopa ninu idije naa, o nilati si a-ka-n-ti naa pelu FCMB.
Omo odun merindinlogun si meedogbon ni o le kopa ninu re.

Oran de po! Iresi derika kan di N900!
Wahala oro aje to de ba Naijiria ti wa fe koja ohun ti apa awon eniyan ka bayii o.
Nnkan ti won koja de gongo, to si je pe ojoojumo lo n won sii.
Ohun to yani lenu ju ni pe ojoojumo naa ni naira n dip onto sii loja.
Enu ya akoroyin IROYIN OWURO kan lose to lo, to si je pe ko le e pa a de nigba to lo si oja to sin a awon ohun jije wo.
Epo pupa ti won gogo, ata ni ki eniyan ma sun mo oun, ti gaari, elubo, semo ati awon nnkan bee bee si n yo ina lenu gege bii Sango Olukoso.
Bi a peere, leyin pe apo iresi kan ti won n ta ni bii egberun mejo naira tele ti dib ii egberun mejilelogun naira (N22,000), iresi derika kan ti di bii aadorun naira!
Nibo wa laa ba yara ja bayii ni ibeere ti awon ara ilu n bi ijoba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…