Tẹlẹ́dàá làṣẹ: Obìnrin tó ń ta pure water bí ìbẹ́ta … láì ṣe iṣẹ́ abẹ
Olorun tun jewo ara re lojo Alaaruba to lo lohun nigba ti arabinrin talakaawa kan, Iyaafin Olivia Plangnaan, bi ibeta lanti-lanti.
Obinrin naa kusee debi pe omi ti a mo si pure water lo n ta ni Abuja.
Funra obinrin naa lo bi awon omo yii ni Osibitu ti a mo si Maitama General Hospital, lai se ise abe.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…