Home ỌRỌ̀-AJÉ Awon ile ise nla nla n wa ire oko lati ra Idi ti o gbodo fi se ise agbe bayii…
ỌRỌ̀-AJÉ - February 18, 2017

Awon ile ise nla nla n wa ire oko lati ra Idi ti o gbodo fi se ise agbe bayii…

Leyin wi pe oye ni yoo kilo fun onitobi, ti ebi yoo soro fun ole, idi pataki ti wa bayii ti onikaluku fi gbodo se ise agbe o.
Idi naa ni pe awon ile ise nla-nla ti won ti maa n ra opo ohun ti won n lo ni ile okeere ni won ko lagbara lati se bee mo.
Aisi owo dola lo fa a .
Nipa bee, won ti wa so awon agbe Naijiria di iyawo, ti won fe fe won bayii.
Awon ti won ti maa n ko ohun ti won fi maa n se fulawa wole tele, awon ti won n ko epo pupa ti won fi n se ose wole, ati awon ti won n ko wiiti ati nnkan miiran ti won fi n se oti lile ati elerindodo ni won ti wa n lo baa won agbe pe ki won wa nnkan ta fun awon.
Ohun ti eyi tumo si ni pe eni to ba n dako bayii, owo gege ni yoo maa ta ire oko re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…