Home iroyin Irú wọ̀bìà wọ̀ńbílíkí wo ni Deizani jẹ́ ná? Abálájọ tó fi na pápá bora
iroyin - February 18, 2017

Irú wọ̀bìà wọ̀ńbílíkí wo ni Deizani jẹ́ ná? Abálájọ tó fi na pápá bora

Kayeefi nla ni oro Minisita fun Oro Epo Robi tele, Iyaafin Deizani Allison-Madueke, si n je fun opo omo Naijiria, latari iwa wobia ti o jo pe o hu nigba to wa ni ijoba pelu Goodluck Jonathan.
Ojoojumo ni won n ri obitibiti owo to ji ko, ti awon ajo EFCC si n topinpin re lo.
Lose to lo ni won tun kana won ile alakopapo estate to tun ko pamo si ilu Eko.
Bee ni won ba owo goboi bilionu, bilionu ninu a-ka-n-ti awon emewa re, ti won si gba pe oun lo ko o sibe.
Loro kan, owo to le ni ogbon bilionu to je tire ni awon adajo to pase pe ki ijoba gbese le bayii.
Ni kete ti Buhari wole ijoba ni Deizani ti sa lo si orile ede Amerika,
Leyin oji bii meloo, o ni oun ti ni arun kansa, to tumo sip e oun fe fi ara mo ilu oyinbo lati wo arun naa san.
Bi o tile je pe won gbe aramonda foto Deizani sita nigba naa, nibi ti o ti gbe hoho, awon eniyan kan si gba pe ogbon awon onitiata ni won da.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…