Home iroyin Ọmọdékùnrin Yorùbá fi arúgbó òyìnbó ṣe aya
iroyin - February 18, 2017

Ọmọdékùnrin Yorùbá fi arúgbó òyìnbó ṣe aya

Mewaa n sele ni ilu oyinbo.
Awon to ba n gbe ibe lo le royin.
Iru ara meriiri naa ti ti omo Yoruba kan to n gbe ni orileede Amerika.
Omodekunrin naa ni Adebiyi Muiz, to fe oyinbo arugbo kan, Iyaafin Susan Smith, ni iyawo.
Pelu bi oju obinrin naa ti ri ninu foto ti Adebiyi te jade, yoo ti le ni eni ogota odun daadaa, nigba ti oun ko si tii lee to eni ogbon odun.
Odun 2015 ni a gbo pe Adebiyi gbe Susan niyawo.
O jo pe ife to wa laarin won gbona gan-an, debi pe won n gbe enu bo ara won lenu ninu foto, ti Adebiyi si n korin ife Asusi re.
Opo eniyan lo so pe idi ti awon omokunrin Naijiria keekeeke se maa n fe awon agbalagba oyinbo ni ki won le ri eni daabo bo won ni ile ajeji.
Se bi oju ba n pon ode niju, a maa fi irawe dana; bi iya ba si n je ode nigbo, a maa sun oro je gege bii isu.
Adebiyi ati Susan, e kare o. Ki Olorun ma pana ife ni adura IROYIN OWURO.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…