Tuface fẹ́ bá ìjọba Buhari fa wàhálà
O ni ki awon eniyan jade fun iwode nla lojo Sunday to n bo
Ilumomika akorin kan, Tuface Idibia, ti kede fun opo awon omo orile ede yii ki won tu jade lojo Sunday ojo karun-un osu keji odun yii, lati fi ehonu han si ijoba apapo ati awon ti iponle lorile ede yii.
Tuface ni bi won se n se ijoba n je ki iya maa je awon omo Naijiria.
O ni won ko ri ojutu oro aje, bee ni owo epo si won gege.
Ominu n ko akorin naa to ko orin AFRICAN QUEEN ati awon opo miiran pea won ijoba ko nifee ara ilu.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…