Home LÁGBO ÀRÍYÁ Wizkid f’àgbà han Davido àti P’Square pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ Grammy
LÁGBO ÀRÍYÁ - February 8, 2017

Wizkid f’àgbà han Davido àti P’Square pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ Grammy

Omo Demola Seriki naa jeun soke

Odun nla, odun itesiwaju nla ni 2016 yii je fun akorin hi hop, Ayodeji Balogun, ti a mo si Wizkid o.
Leyin igba to ti gba awon ami eye nla nla bii akorin to gbona julo ni AFRIMA ati MAMA, awon oyinbo Amerika tun ti yan an gege bii okan lara awon ti o seese ko gba ami eyey ninu asekagba Grammy Awrds to maa waye ninu osu keji odun to n bo.
Lara awon akorin to ti sun mo Grammy bee ni King Sunny Ade ati Femi Kuti.
Pelu itesiwaju ti Wizkid ti ni, o jo pe o ti sekona mo awon akegbe re bii Davido, D’Banj, Tiwa Savage ati P’Square lowo.
Won yan an fun asekagba Grammy latari ipa yto ko ninu orin akorin oyinbo kan ti a mo si Drakes.
Bakan naa, Faridah, to je okan lara awon omo oloselu APC kan, Oloye Demola Seriki, wa lara won ti won yan fun asekagba Grammy naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…