Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Túndé àti Wùnmí be fẹ́ kọ́ àwọn ènìyàn ní eré ìfẹ́
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - December 25, 2015

Túndé àti Wùnmí be fẹ́ kọ́ àwọn ènìyàn ní eré ìfẹ́

Ti toko-taya akorin ti a mo si Tunde ati Wunmi Obe, ti adape won n je TWO, ba n so nipa oro ife, o ye ki eniyan maa feti bale daadaa.

Idi ni pe won je okan lara awon gbajugbaja osere ti won mu ife aisetan ati igbeyawo aladun ni okunkundun.

Opo awon alariya ni igbeyawo won kii ka odun to fi maa n tuka.

Sugbon awon mejeeji yii, tipe-tipe-n-tiran ni won, bi igbin ba fa, ikarahun a tele e ni.

Idi niyi ti awon naa kii fii dake lasiko ayajo odun ifeValentine, eyi ti yoo waye lojo kerinla osu yii.

Lojo naa ni ilu Eko, won yoo gba opo eniyan lalejo pelu orin, ilu, ijo ati orisiirisii eto miiran.

Atejade kan lati ile ise won fi yeni pe Ile itura Renaissance Hotel, ni Alausa, Ikeja, ni ayeye naa yoo tiwaye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…