Home LÁGBO ÀRÍYÁ Adékúnlé Gold ń múra ìgbéyàwó
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 24, 2015

Adékúnlé Gold ń múra ìgbéyàwó

Orisirisii ona ni omokunrin to ba ti balaga fi maa n mura sile fun igbeyawo.
Nigba ti awon miiran yoo maa foju sode, elomiiran yoo so fun awon to ba sun mo o pe ti won ba ri omo to dara, ki won ma gbagbe oun.
Ni ti akorin igbalode to n rowo mu bayii, Adekunle Gold, ohun to n se ni pe o n wo ewu iyawo sile ni.
Adekunle Gold ko sinu ofi nla kan lose to lo, owa n ro o jade pea so naa yoo ye oun lojo igbeyawo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…