Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Odun yi o ye! Ambode fe ta iresi Keresi ni edinwo
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - September 17, 2015

Odun yi o ye! Ambode fe ta iresi Keresi ni edinwo

Ijoba Ipinle Eko ti gbe ara miiran de o, lori odun Ketesi ati Odun Nla New Year to n bo lona yii.
Pelu bi nnkan se won gogo, ijoba naa mo pe opo eniyan ni ko le rowo ra iresi nigba ti apo kan ti dib ii egberun lona ogun naira tabi ju bee lo.
Ijoba Ambode ti wa ko iresi opo yanturu wolu, ti a gbo pe won yoo ta ni edinwo.
Iroyinfi ye w ape bii egberun meedogun naira (N15,000) ni won yoo ta apo kan.
Pelu igbese yii, Ambode tun ti fihan pe oloselu to nifee si idunnu ara ilu ni oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…