Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ
Awon omo Alade yari: Yoruba fe gba’ra re lowo ajeji Fulani to n tele basubasu
. Akeredolu yari kanle . Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe . Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili . Sunday Igboho si gegun kale Igbaniloju naa ti n lo, ojo pe die, sugbon bayii, o jo pe ile Yoruba ti setan ati gba…
Read More »Ìjo̩ba máa gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú àwo̩n oníròyìn ìdàlúrú – Lai Mohammed
Ìjo̩ba máa gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú àwo̩n oníròyìn ìdàlúrú – Lai Mohammed Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji Lai Mohammed ni ijoba apapo ko ni gba ki awon kan fi iroyin aboosi da ilu ru. O ni “oloju ko ni laju…
Read More »Lai Mohammed pe Yorùbá níjà
Iforo-wa-ni-lenu wo laarin Minisita eto iroyin ati asa, Alhaji Lai Mohammed pelu Iroyin Owuro. Minisita ni ki a ma se gbagbe isese wa, Baba yii ni ki a fi gbogbo olaju gbe isese ati asa wa laruge. Iroyin Owuro – Ki a maa baa maa fi gbogbo igba beere nipa…
Read More »Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki
Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki Lati owo Yinka Alabi Ijoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck Jonathan maa wa jejo lati ile ni…
Read More »Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu
Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu Fẹ́mi Akínṣọlá Kángun kàngùn Kángun, bọ́ pẹ́,bọ́ yá, ó gbọ́dọ̀ kángun síbìkan, bẹ́ẹ̀ ló súmọ́ kí ọ̀rọ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, látàrí àgbéjáde ilé ẹjọ́. Tí Ilé ẹjọ́ kan kò bá wá fìdíi ọ̀rọ̀ múlẹ̀ ní pàtó…
Read More »Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́
Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ìgbésẹ̀ òhun ìhùwàsí oníkálùkù láàyè, ìtàn ló ń kọ lóké eèpẹ̀. Tẹbi tara tọ̀rẹ̀ àti àwọn èèkan nísẹ́ Ìjọba ló péjú láti ṣé ajọyọ̀ ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bí ọdún karundinlọgọrin gomina tẹlẹri nipinlẹ Ọyọ, Oloye Rashidi Adewọlu Ladọja. Ayẹyẹ…
Read More »E̩ tu èékánná lára S̩owore – Ilé-e̩jó̩
Ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja lo pase fun ijoba apapo pe ki won yokun lorun Ogbeni Omoyele Sowore. Sowore ni o n gbimo lati se iwode Kan to maa mi ilu titi. Lati igba naa ni ijoba apapo ti fi owo sinkun ofin mu u. Ogbeni Sowore…
Read More »Makinde kò tíì yí àṣẹ àfàró padà lórí i ẹgbẹ́ awakò NURTW ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Makinde kò tíì yí àṣẹ àfàró padà lórí i ẹgbẹ́ awakò NURTW ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ẹ ma fori ọka họmú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe ko ko ko bayii la a ranfa fẹni eti n yọ lẹnu,idi niyi ti Ijọba ipinlẹ Ọyọ fi soju abẹ niko pe ,ko sohun to yipada lori…
Read More »Fashola kìí se minisita iná mó.
Babatunde Fashola kii se minisita ina (power) mo. Nigba ti won n se inagije awon miniwni ọsan oni, Aare Buhari kede Sale Mamman ti o je omo ile Taraba gege bi minisita ina. Amo Fashola si di ipo re gege bi minisita ise ati ile mu.
Read More »Wọ́n ti ṣe inagije fún àwọn minisita.
Won ti se inagije fun awon minisita lonii ni ile ipinle. Oruko awon minisita ti won yan naa ni wonyi; Ekiti- Otunba Adeniyi Adebayo Enugu- GeoffreyOnyeama Gombe- Isa Ibrahim Pantami Imo- Emeka Nwajiuba Jigawa- Sulieman Adamu Kaduna- Zainab Ahmed Kaduna-Mohammed Mahmud Kano- Sabo Nanono Kano- Major Bashir Magashi Katsina/Hadi…
Read More »