ỌRỌ̀-AJÉ
Yègèdè! Adénúgà di ẹni ọdún mọ́kàndín-láàdọ́rin
Mudasiru Alabi Idunnu n subu lu ayo ninu ile gbajugbaja onise okowo to tun je olowo tabua, Dokita Mike Adenuga, tori pe o ti pe eni odun kan din laadorin – 69 years bayii. Dokita Adenuga je akanda eda to da ile ise Globacom sile, nibi ti opo eniyan ti…
Read More »NAFDAC ti ti àwọn ilé iṣẹ́ tí wọ́n fi oògùn òkú toju ponmo.
National Agency for Food and Drug Administration and Control, NAFDAC, ti ti awon ile ise meta ti won ko ponmo wo ilu ti won wa ni Unity Avenue, Ijagemo; Sosanya Street ni Ijegun ati Adedayo Street ni WAZOBIA Bus Stop ni Abaranja, ti gbogbo wa labe Alimosho local government area…
Read More »Àwọn olè ti pa àwọn ọlọ́pàá méjì tí ń tẹ̀lé ọkọ̀ owó ní Ìpínlẹ̀ Port Harcourt.
Awon ole ti yin ibon pa awon olopaa meji ti won so mo ile ise ti n pin oti beer ti o wa ni Nwachukwu/Ojoto street ni Port Harcourt, Rivers ni aaro ojo Monday. Awon ole naa ko owo lo, won si yin ibon pa awon olopaa ti n tele…
Read More »Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ lo tí jóná lẹ́yìn tí ọgbà mẹkáníkì gbiná.
Awon makaniiki kan n banuje lowo leyin ti ogba mekaniiki kan ni oregun, ipinle Eko ti gbina. Opolopo oko ni won si padanu. Ina naa bere ni owo aaro mo osan eni June 29.
Read More »Àwọn tí wón ń yọ́ ọjà gbé w’ọ̀lú ti yín ìbọn pá òṣìṣẹ́ custom, Yakubu Shuaibu sínú igbó.
Awon ti n yo oja gbe wolu (smugglers) ti yin ibon pa osise custom, Yakubu Shuaibu sinu igbo ni ipinle Ogun. Gege bi agbenuso Nigeria Customs Service (NCS), Federation Operations Unit (FOU), Zone A, Jerry Attah se so, ofisa miiran farapa leyin ti awon eni yii duro de won lona…
Read More »Ilé ẹjọ́ ti j’áwèé pé kí wọ́n lọ gbé ọ̀gá ilé isẹ́ Innoson, Innocent Chukwuma.
Ile ejo ni Ikoyi, ipinle Eko ti ja iwe pe kinwon lo gbe oga ile ise Innoson Nigeria Ltd, Innocent Chukwuma ati awon meji miiran fun esun jibiti. Adajo Ayokunle Faji lo fi eyi lile ni ojo Mondsy June 24, ti o ni ki won gbe oga ile ise Innoson,…
Read More »Arákùnrin pàdé ikú òjijì nígbà tí ó ń gbìyànjú láti sá fún àwọn imigiráṣọ̀n ní Indonesia.
Arakunrin omo Naijiria, Ije Nwoke ti ku si orile-ede Indonesia. Ore re ti o gbe iroyin naa si oti afefe ni “oko lo gba, nigba ti o n gbiyanju lati sa fun imigiráṣọ̀n ni Tangerang ni Indonesia”.
Read More »NAFDAC tí gbẹ́sẹ̀ lé títa oògùn p’ẹ̀fọn (Sniper) ní ọjà.
The National Agency for Food, Drug Administration and Control (NAFDAC) ti gbese le tita oogun p’efon (sniper) laaarin oja. Adari NAFDAC, Veterinary Medicine and Allied Products Directorate, Dr. Bukar Usman, ti so ni ojo Wednesday pe International Institute of Tropical Agriculture (IITA), Ibadan ni ki awon ti n ta Sniper…
Read More »Femi Otedola ti kúrò ní ilé isẹ́ Forte Oil.
Onisowo onibilionu, Femi Otedola ti so pe oun ti kuro ni ile ise Forte Oil. Eyi waye leyin osu die seyin ti o ni oun maa ta ṣiẹsi oun fun Predunt Energy, ile ise epo si ni. Otedola to je alaga ti o si ni siesi to poju ni ile…
Read More »Èèyàn mẹ́ta tí jàre ikú bí ilé mìíràn ṣe wó ní Eko.
Ile oloke kan ti wo lule ni agbegbe Shingisha, Magodo ni ipinle Eko. Gege bi iroyin se si, won n ko ile naa lowo nigba to se o ni ojo Thursday, tibeeyan meta si wa ninu re. Ile naa wo lule ni Kayode Aluko Olokun closeni Shangisha, Magodo. O wo…
Read More »