Orisirisi
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìkan dárìn,bí kò ju bíntín, yóó fọwọ́ kọ́ nǹkan . Ó ti ń fojú hàn pé rúkèrúdò mí-ìn ti ń kànkù gbọ̀ngbọ̀n báyìí nínú ẹgbẹ́ àwọn awakọ̀, tí amọ̀ sí “NURTW” bí wọ́n ṣe ní…
Read More »Agbébọn mọ̀ọ́mọ̀ pa àwọn aláwọ̀dúdú mẹ́wàá ní ilé itájà ní New York ni – Major
Agbébọn mọ̀ọ́mọ̀ pa àwọn aláwọ̀dúdú mẹ́wàá ní ilé itájà ní New York ni – Major Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí orí máa kóni yọ ninú ewu gbogbo,kó sì là wá lọ́wọ́ àwọn oníkòórìíra àti abínú ẹni. Ní bàyìí,Olóòtú ìlú Buffalo ti fèsì sí ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé ní New York l’Amẹ́ríkà…
Read More »Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ
Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìpàdé tó wáyé láàrin ìjọba àpapọ̀ àti ẹgbẹ́ olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì, ASUU ní àná òde yìí ni ó forísánpọ́n lẹ́yìn tí àwọn ikọ̀ méjèèjì kúnà láti se àtúnse lórí ọ̀rọ̀ ìyansẹ́lódì tí wón gùn…
Read More »Ìtumò̩ ò̩rò̩-orúko̩
Ìtumò̩ ò̩rò̩-orúko̩ E̩ jé̩ kí á ní ìmò̩ kún ìmò̩ wa ní ìkànnì Ô̩TÒ̩LÓRÌN. E̩ wo fídíò yí.
Read More »Ẹ kọ̀wé fipò sílẹ̀ láti ráàyè dupò tẹ́ ẹ fẹ́—Muhammadu Buhari
Ẹ kọ̀wé fipò sílẹ̀ láti ráàyè dupò tẹ́ ẹ fẹ́—Muhammadu Buhari Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní a kìí jẹ méjì lábà Àlàdé. Ààrẹ Orílẹ̀ yìí Muhammadu Buhari ti pàṣẹ fún gbogbo àwọn mínísítà rẹ̀ láti kọ̀wé fi ipò wọn sílẹ̀ ti yóó bá fi di ọjọ́ kẹrìndínlógún, oṣù…
Read More »Ẹnú wà ṣọkan,kò sí ẹni tí kò lè dije ipò ààrẹ láti ilẹ Yorùbá—-Bisi Akande
Ẹnú wà ṣọkan,kò sí ẹni tí kò lè dije ipò ààrẹ láti ilẹ Yorùbá—-Bisi Akande Ọrẹ Òtítọ́jù Ìpàdé àwọn èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC nílẹ̀ ẹ Yorùbá ti wá sópin nílùú Èkó. Alàgbà Bisi Akande tó darí ìpàdé yìí sì ti ní ẹnu àwọn kò lórí i pé kí ẹkùn ìwọ̀…
Read More »Ẹ múra kí ẹ gba ìpínlẹ̀ Eko lọ́wọ́ àwọn àjòjì – Atiku
Ẹ múra kí ẹ gba ìpínlẹ̀ Eko lọ́wọ́ àwọn àjòjì – Atiku Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní n tí ó bá jẹni lógún n náà ní-ín pọ̀ lọ́rọ̀ ẹni. Igbákejì Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tó tún jẹ́ olùdíje sípò Ààrẹ Nàìjíríà, Alahji Atiku Abubakar ti pàrọwà…
Read More »Ìrìn rẹ ò nítumọ̀, tó ò bá sàbẹ̀wò sí àgbègbè tí Fulani ti ń ṣe ọṣẹ́ ní Nàìjíríà—Akintoye
Ìrìn rẹ ò nítumọ̀, tó ò bá sàbẹ̀wò sí àgbègbè tí Fulani ti ń ṣe ọṣẹ́ ní Nàìjíríà—Akintoye Ọrẹ Òtítọ́jù Olórí ẹgbẹ́ tó ń jà fún ìdásílẹ̀ orílè-èdè Odùduwà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Bánjí Akíintóyè, ti késí akọ̀wé àjọ United Nations, Antonio Gueterres, láti la ojú rẹ̀ sílẹ̀, kó rí àwọn nǹkan tó…
Read More »Ẹni aráàlú bá fìbò yàn ni ààyò mi—Ààrẹ Buhari lórí
Ẹni aráàlú bá fìbò yàn ni ààyò mi—Ààrẹ Buhari lórí Fẹ́mi Akìnṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní lẹ́nu ọlọ́fà la tií gbọ́ mọ ta á. Ààrẹ Muhammadu Buhari ti jiyàn àhesọ ọ̀rọ̀ to wí pé ó ní ààyò nínú gbogbo àwọn olóṣèlú tí wọ́n ti fi èròńgbà wọn léde láti di…
Read More »Àsìkò ẹkù ìhà Gúúsù nìyí láti jẹ ààrẹ – Gómìnà Akeredolu
Àsìkò ẹkù ìhà Gúúsù nìyí láti jẹ ààrẹ – Gómìnà Akeredolu Ọrẹ Òtítọ́jù Ṣé àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ọ̀rọ̀ tó bá dánilójú, kìí kọsẹ̀ létè ẹni. Alága àjọ àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ ẹkùn Gúúsù Orílẹ̀ yìí, Rotimi Akeredolu ti ké sáwọn adarí ẹgbẹ́ òṣèlú APC láti máṣe fa ọ̀rọ̀ gùn lórí…
Read More »