òpómúléró
Yègèdè! Adénúgà di ẹni ọdún mọ́kàndín-láàdọ́rin
Mudasiru Alabi Idunnu n subu lu ayo ninu ile gbajugbaja onise okowo to tun je olowo tabua, Dokita Mike Adenuga, tori pe o ti pe eni odun kan din laadorin – 69 years bayii. Dokita Adenuga je akanda eda to da ile ise Globacom sile, nibi ti opo eniyan ti…
Read More »El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn
El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn Ìròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Nnkan buruku sele ni ilu Giwa ati Igali ni oru ojo aiku moju ojo Aje. Awon adihamora ni won tun ya bo awon ilu ati abule ni ipinle Kaduna ti won si bere si pa awon eniyan ibe,…
Read More »Àwòrán Aláàfin Ọ̀yọ́ àti àwọn ìyàwó rè.
Aworan Alaafin Oyo ati awon iyawi re nigba ti won se ayeye Eid-Mubarak in ipinle Oyo ni ana August 12.
Read More »Ìgbìmò tí Saraki darí ti d’ínà ìjẹ́rìí Magu nítorí àṣepamọ wọn – Alaafin Oyo.
Alaaafin Oyo Oba Lamidi Adeyemi III, ni ojo Thursday August 1 ti fi esun kan igbimo ti Saraki dari pe won dina ijerii Ibrahim Magu gege bi Alaga Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) nitori ohun ikoko ti won se pamo. Alaafin so eyi nigba ti o se ipade pelu…
Read More »America ti fi ìhámọ́ sí orí físà fún àwọn olóṣèlú Nàìjíríà.
Orile-ede America ti kede ni ojo Tuesday pe won ti fi ihamo si oti fisa fun awon oloselu Naijiria ti won lero pe won le da idibo 2019 ru. Won o darulo ninu ikede naa, amo awon ti oro naa bawi ni awon ti won lowo ninu iwa ipanle ninu…
Read More »Ọmọ Gomina Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àná, Abiola Ajimobi ti jáde ilé ìwé gíga.
Gomina ipinle Oyo ana, Abiola Ajimobi ati iyawo re, Florence Ajimobi n se ajoyo lowo leyin ti okan lara omo won obinrin, Ajijola, jade lati University of Warwick ni United w. O gbe iwe eri Bachelor of Art in History and Sociology. A ki won ku ori ire.
Read More »Wọ́n ti ṣe ìsìnkú Funke Olakunrin.
Won ti se isinku Oloogbe Funke Olakunrin, omo olori egbe Afenifere, Pa Reuben Fasoranti, ni St. David’s Anglican Church Ijomu, ni Akure, ipinle Ondo ni ojo Monday July 22. Awon ti won wa ni ibi isinku naa ni Gomina ipinle Ondo, Arakunrin Oluwarotimi Akeredolu, ati awon elegbe re lati Ogun,…
Read More »Àìláábò: Alaafin kọ ìwé-ẹ̀dùn sí Ààrẹ Buhari.
Alaafin Oyo, Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi III, ti ko iwe edun si Aare Muhammadu Buhari nipa ipa odi ti aini aabo ni si Naijiria, paapaa ni Gusu Ila-Oorun, o si n kilo pe ilana ijoba asaaju o ti i wo patapata ni ile Yoruba. O so pe opolopo orile ede…
Read More »Adarí NYSC ti ní òun ma ran Àgùnbánirọ̀ ti o farapa lọ́wọ́.
Adari NYSC, Brig-Gen. Shuaibu Ibrahim, ti se ileri ni ojo Wednesday fun ise, owo ike meji(limbs) ati iranlowo fun Nurudeen Tahir, agunbaniro fi o farapa ninu ijamba oko leyin ti o kuro ni kampu ni Jalingo, ipinle Taraba. Ibrahim, ti o se ileri nigba ti o lo ki Tahir ati…
Read More »Ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Dolapo Osinbajo, iyawo Igbákejì Ààrẹ Yemi, ti pe omo odun mejilelaadota lonii July 15. O gbe aworan ojo ibi re akoko si ori instagram, o si n dupe lowo olorun fun ojo ibi naa. O ni: Mo dupe lowo olorun fun ojo ibi miiran . Ojo ibinmi akoko A f’ope…
Read More »