iroyin
E̩nu bode kò wà ní títì pátápátá – Hameed Ali
E̩nu bode kò wà ní títì pátápátá – Hameed Ali Lati owo Yinka Alabi Ajo asobode ile wa ti gbogbo aye mo si Customs ni won tun ti gbese le awon oja to lodi sofin ti owo re le ni milionu meji naira. Ibi ti oga patapata ajo naa ti…
Read More »Òmìnira yin ti dé – Buhari
Aare orileede yii, Alhaji Mohammed Buhari lo n fi gbogbo omo Naijiria lokan bale pe irorun ti de. Nibi ayeye ikini ku odun ominira ti Naijiria fi pe odun mokandinlogota ni Aare ti n salaye yii. Aare ni eyi ni o je ki ijoba apapo da ajo ati ile-ise miran…
Read More »Ẹ kó owó tí kò dára lọ sí báǹkì – CBN.
Central Bank of Nigeria (CBN) ti so fun awon omo Nigerja pe ki won ko gbogno owo ti ko ba dara mo lo si ile ifowopamo ki o to di ojo Monday, September 2. CBN ni idi ti won fi so eyi ni lati paro awon owo ti ko…
Read More »Wọ́n ti pa ọmọ Nigeria ni South Africa.
Won ti pa arakunrinomo Nigeria omo odun merindinlaadota ti n je Pius Ezekwem, ti n gbe ni Easthern Cape ni orile-ede South Africa. Gege bi iroyin se so, Pius ti o ni ile itura ti o fi n sise,ni awon olopaa mejo gbe nibi ti o ti n jeun…
Read More »Wọ́n ti fi owó kún owó físà America.
Embassy orile ede America ni Nigeria ti so pe lati ojo Thursday, August 29 odun yii, awon omo Nigeria ti o ba fe gba fisa a ma a san $110(40,700) lati gba fisa won ti won ba fun won. Eyi yato si owo fisa 59,200 naira ti won n…
Read More »Wọ́n ti mú àwọn ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn.
Awon osise Operation Crush lati eka Anti-Cultism ti mu awon marundinlogbon ti won fura si pe won je elegbe okunkun ni agbegbe Ijora, Mushin ati Bariga ni ipinle Eko laaarin ojo kan. Agbenuso olopaa ipinle Eko, Bala Elkana, ti fihan ninu gbolohun ti o fi kale pe ason oludaabo…
Read More »Fashola kìí se minisita iná mó.
Babatunde Fashola kii se minisita ina (power) mo. Nigba ti won n se inagije awon miniwni ọsan oni, Aare Buhari kede Sale Mamman ti o je omo ile Taraba gege bi minisita ina. Amo Fashola si di ipo re gege bi minisita ise ati ile mu.
Read More »Wọ́n ti ṣe inagije fún àwọn minisita.
Won ti se inagije fun awon minisita lonii ni ile ipinle. Oruko awon minisita ti won yan naa ni wonyi; Ekiti- Otunba Adeniyi Adebayo Enugu- GeoffreyOnyeama Gombe- Isa Ibrahim Pantami Imo- Emeka Nwajiuba Jigawa- Sulieman Adamu Kaduna- Zainab Ahmed Kaduna-Mohammed Mahmud Kano- Sabo Nanono Kano- Major Bashir Magashi Katsina/Hadi…
Read More »Aare Buhari ti yan àwọn minisita metalelogiji.
Aare Buhari ti yan awon minisita metalelogiji ni osan, oruko won ati ipo won naa si ni wonyi, Abia- Uchechukwu Samson Ogah: Minisita fun igbaja Mines ati Steel ipinle Adamawa- Mohammed Musa Bello: Minisita fun Federal Capital Territory Akwa Ibom- God’swill Akpabio: Minisita fun Niger Delta Anambra- Dr Chris…
Read More »EFCC ti lọ sí ilé Akinwunmi Ambode.
EFCC ti lọ sí ilé Akinwunmi Ambode. Awon osise Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) ti lo si ile gomina ipinle Eko ana, Akinwunmi Ambode. Awon osise naa lo si ike Ambode ti o wa ni Epe ni won lo ni ago mesan-an aaro oni, won si n tu ile…
Read More »