ERÉ ÌDÁRAYÁ
Ronaldinho ń kó̩ is̩é̩ gbé̩nàgbe̩nà nínú è̩wò̩n ní orílèèdè Paraguay
Ronaldinho ń kó̩ is̩é̩ gbé̩nàgbe̩nà nínú è̩wò̩n ní orílèèdè Paraguay Lati owo Akinwale Taophic Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni akoko ninu boolu alafesegba kaakiri agbaye, Ronaldinho, ti wa ninu Ewon ni orileede Paraguay bayii lati nnkan…
Read More »Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá
Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! Gudugudu meje ati yaaya mefa ti atamatase fun orileede wa…
Read More »Olùkó̩ni Arteta ti rí ìwòsàn
Olùkó̩ni Arteta ti rí ìwòsàn Lati owo Akinwale Taophic Olukoni fun egbe agbaboolu Arsenal ni orileede England, eni ti okiki kan kaakiri ni bi ose meji seyin wi pe o ti ni aisan Coronavirus, Mikel Arteta, ni o ti je ki o di mimo ni owuro ojo aje ti o…
Read More »Àjo̩ UEFA ti sún ìdíje Champions league àti EUROPA síwájú
Àjo̩ UEFA ti sún ìdíje Champions league àti EUROPA síwájú Lati owo Akinwale Taophic Leyin ipade oro siso lati ori ero amohun-maworan ayelujara eyi ti ajo UEFA ati gbogbo awon ti oro idije Uefa Champions league ati Europa League gberu se ni Owuro ojo aje ti o koja lo yi,…
Read More »Patric Mboma pàdánù è̩gbó̩n re̩ só̩wó̩ àrùn Coronavirus
Patric Mboma pàdánù è̩gbó̩n re̩ só̩wó̩ àrùn Coronavirus – Lati Owo Akinwale Taophic. Agbaboolu ni igba kan ri fun orileede Cameron, ti o je oguna gbongbo ti n dato lenu igbin ti a ba n soro nipa boolu alafesegba ni ile adulawo ajaaja ni orileede abinibi re Cameron, Patrick Nboma,…
Read More »Valencia fìyà je̩ Barcelona lójú Coach tuntun
Valencia fìyà je̩ Barcelona lójú Coach tuntun Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo ogun le fun iko agbaboolu Barcelona laipe yii nigba ti egbe agbaboolu Valencia gbo ewuro si won loju pelu ami ayo meji, ti won ko si le da okankan pada. Barcelona gbiyanju gan-an ni abala akoko idije naa,…
Read More »Mánigbàgbé eré bó̩ò̩lù – Atlanta 1996
Manigbagbe boolu “Atlanta 1996” Yinka Alabi Ere boolu yii waye ni odun naa nigba ti Oloogbe Sani Abacha n tuko orileede yii. Bonfere Jo ni akonimoogba, Kanu Nwankwo si ni olori awon agbaboolu. Gbogbo igba ni iko Super Eagles maa n je iya lowo orileede Brazil. Ti ojo naa tun…
Read More »Nigeria yóò gba milionu nara lona 714 fún ipò kẹta ni AFCON 2019.
Awon Super Eagles Nigeria yoo gba milionu naira lona 714(714milkionu naira) to je milionu dollar meji(2million dollars) lowo Confederation of African Football (CAF)fun pe won kopa ninu 2019 Africa Cup of Nations (AFCON) ati pe won gba ipo keta. Nigeria gba 1-0 pelu Tunisia, ti o fun won ni ipo…
Read More »Algeria do̩ba Afirika
Iko agbaboolu orileede Algeria jawe olubori ninu idije boolu alafesegba ti odun 2019, eyi waye ni orileede Egypt. Iko yii naa ni o na orileede Naijiria ni ami ayo Kan nibi idile naa nigba ti orileede ku merin pere. Orileede Senega ni Algeria na ni ami ayo Kan ni eyi…
Read More »Odion Ighalo ti fẹ̀yìntì.
Agbaboolu omo ile Naijiria, Odion Ighalo ti fẹ̀yìntì ninu boolu oke okun fun Super Eagles, yoo si ma se ikede laipe, leyin ijade aseyori ni 2019 African Cup of Nations. Agbaboolu naa lo gba gba goolu fun Naijiria ti a fi de ipo keta, leyin ti Nigeria ati Tunisia pade…
Read More »