ÀRÒJINLẸ̀
Ojúmọ́ kan, oògùn kan
Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko leta si Aare to maa dogun dode. Lenu odun yii…
Read More »Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo…
Read More »Àbá Àseyorí 2020
Gbogbo eyin alarojinle, e ku ojo meta. Eledua ko ni je ki a su ara wa. Awa ti a foju wina ipenija ilu yii naa lo maa je oro ilu naa lase Edumare. Bi ere bi awada, odun 2019 keru nile, o maa di oro itan laarin wakati meloo kan…
Read More »Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná
Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná Lati owo Yinka Alabi Iya agbalagba ti ko din ni aadorin odun lo lo roo pin si ofiisi ajo apina-ka (IBEDC) Ibadan Electricity Distribution Company to fi ikale si ilu Osogbo. Mama yii di awon nnkan to le nilo ti…
Read More »Àsírí Òkété
ÒKÉTÉ. ___ Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀. Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò le rí èrùpẹ̀ lẹ́nu isà òkété, bí…
Read More »Ara kò rokùn…
Eyin alarojinle, e ma ku ojo meta. Ilu lilu toni o ki n se ilu alujo rara. Eto aabo Orileede yii ni o n ko gbogbo wa lominu. Eni to ba si ni oro naa ko kan oun, boya lo mo pe, nigba to kan oun tan, o tun se…
Read More »Ìjà tí wáyé ní pápá ọkọ̀ -òfuurufú ti Abuja.
Ija ti be sile ni Nnamdi Azikiwe Airport ni Abuja. Gege bi iroyin se so, a gbo pe iya naa waye laaatin awon ti won fe wo oro ofurufu ti Airpeace, awon ti n lo si Enugu atinawon ti n lo si Eko n ja si eni ti o ma…
Read More »Arábìnrin ti fi ìyà jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ nítorí ó ké pe ìrànlọ́wọ́.
Laaarin awuyewuye ti n lo lowo nipa ifipabalopo, orisirisi obinrin lo ti n so awon nnkan ti oju won ti ri seyin nipa ifipabalopo. Bee ni a si ri awon obinrin miiran ti won ko ni aanu obinrin bi egebe won. Arabinrin kan, Agatha Ayerite, ti so lori Facebook bi…
Read More »Ìyá ti fi oògùn p’ẹ̀fọn(sniper) pa ọmọ rẹ̀.
Arakunrin kan @aproko_doctor ti so lori twitter bi iya se fi oogun p’efon si ori omo re lati pa kokoro ti o wa ni ori re, ti o si gba emi omo naa. O ni “ mo sese gbo itan ti o banileru nipa iya ti o fi oogun p’efon…
Read More »Bàbá tí ọmọ rẹ̀ pa fún ogún ọdún nítorí wárápá.
Arakunrin omo odun metalelogun, ti o n je Basty Abass, ti wa ni atimole fun ogun odun ni Nkwanta south ti Oti region, ni orile-ede Ghana, ti a gbo pe baba re ti mole nitori o ni warapa. A gbo lati oju feresi nikan ni Abass ti ma n…
Read More »