Home ÀKỌ̀TUN Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - February 28, 2021

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Ọrẹ Òtítọ́jù

Aja-fẹtọọ’mọniyan ati ajijagbara, Sunday Adeyemo, ti ọpọ mọ si Sunday Igboho ti ṣabẹwo si Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba, Gani Adams, ni ile rẹ to wa niluu Eko.

Bo tilẹ jẹ pe a ko le sọ ni pato eredi ipade ọhun, ṣugbọn ọpọ awọn ọmọ Yoruba lo ti bẹrẹ si n sọ pe ipade ọhun ko ṣẹyin ọrọ eto abo ilẹ Yoruba ati
awọn Fulani darandaran.

Oniruuru ariwisi yii naa lo n fidii rẹ mulẹ pe ara o rọ
okun, ara o rọ adiẹ lori eto aabo orilẹ yii.
Awọn ti eto aabo gbe ru papa a n ke tantan pe ki nnkan ma bajẹ ṣugbọn ,o jọ pe ebọ kabiti ni iroko ti wọn o tete pẹka rẹ yii n fojoojumọ beere lọwọ ọ wọn, leyii to si n fa laasigbo leto oṣelu ohun ọrọ aje.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá?

Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá? E̩ wo fídíò ìsàlè̩ yí, kí e̩ …