Home ÀKỌ̀TUN E̩ má da òsèlú pò̩ mó̩ ètò ààbò – O̩o̩ni Ile-Ife̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - January 27, 2021

E̩ má da òsèlú pò̩ mó̩ ètò ààbò – O̩o̩ni Ile-Ife̩

E maa da oselu po mo aabo ilu – Ooni ti Ile-Ife

Yoruba bo, won ni ” agba kii wa loja ki ori omo tuntun o wo”. Eyi lo mu ki Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi te oko leti lo ilu Abuja.
Ibi ipade pelu Aare ni Ooni ti n salaye yii pe ki awon ara ilu jowo ma se da oro oselu po mo eto aabo. O ni won ko jo ara won rara.
Kabiyesi ni oselu kun fun ote, tenbelekun ati ipanle. O ni eto aabo gbodo je ajose gbogbo ara ilu. O ni gbogbo eniyan le maa ni ife si oselu sugbon gbogbo eniyan lo gbodo lowo si eto aabo.
Aare Mohammadu Buhari naa tun ran Ooni si awon Oba ile Yoruba to ku. O ni Aare ni ipade eto aabo gbogbo maa lo loorekoore pelu awon ara ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…