Ìyàwó Igbákejì Ààrẹ Yemi Osinbajo, Dolapo Osinbajo ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀.
Dolapo Osinbajo, iyawo Igbákejì Ààrẹ Yemi, ti pe omo odun mejilelaadota lonii July 15.
O gbe aworan ojo ibi re akoko si ori instagram, o si n dupe lowo olorun fun ojo ibi naa.
O ni: Mo dupe lowo olorun fun ojo ibi miiran
. Ojo ibinmi akoko
A f’ope f’olorun
. L’okan ati l’ohun wa
. Eni s’ohun ‘yanu…..
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…