Home Orisirisi Eemo, dokita di adigunjale ni ilu Abuja
Orisirisi - February 18, 2018

Eemo, dokita di adigunjale ni ilu Abuja

Nigba ti a maa n ka iwe Alawiye Yoruba nijoun, okan lara awon itan inu re ni itan Aworawo ko kan tise, ibi ori eni ba ni a maa de, a ko ni sai debe. Bakan naa ni itan Aworawo di aponmita.
Isele kan to n sele lowo nilu Abuja bayii le mu ki opo eniyan ranti itan yi. Isele naa ni ti okunrin dokita oyinbo kan, Jimade Ola-Solomon, ti o je oludasile Viital Care Hospital.
Ni bayii, awon olopaa ti n wa a kiri tori won ni o kan n fi ise dkita boju ni. Won ni adigunjale paraku ni.
Se loooto wa ni eyi abi nnkan miiran? Oro naa si n ko opo eniyan ni ‘Haa.’ Won ni se loooto ni Dokita di adigunjale nilu Abuja.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…