Home Orisirisi Tinubu fi Obasanjo ati Babangida se yeye lori leta ti won ko si Obasanjo
Orisirisi - February 14, 2018

Tinubu fi Obasanjo ati Babangida se yeye lori leta ti won ko si Obasanjo

Olori Egbe APC, Asiwaju Bola Tinubu, ti fi awolori orile-ede yii meji tele, Oloye Olusegun Obasanjo ati Ogagun Ibrahim Babangida, pa miidin lori leta ti won ko si Aare Muhammadu Buhari, nibi ti won ti so fun Buhari pe ko gbodo gbe apoti leekeji ni 2019.
Tinubu so pe won kan n pala enu ni.
O ni dipo ti won o fi maa so isokuso, o ye ki won lo darapo mo awon afeyinti lenu ise ijoba ati oselu ni.
O ni loooto ni wahala po lorun Naijiria, sugbon ijoba APC ti n yanju re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…