Home iroyin Orileede Austria fi egberun omo Naijiria ranse sile
iroyin - February 8, 2018

Orileede Austria fi egberun omo Naijiria ranse sile

Ti iya nla ba gbe ni sanle, keekeeke naa maa gori re ni oro Naijiria ri. Orileede kekere ti o n je Libya ni o n fi ipa le awon omo Naijiria sile lati bii osu mefa seyin bayii.
Oni ode yii ni awon orileede Austria naa fi egberun omo Naijiria ranse ni tipa ti ikuuku. Won ni ibagbe awon omo Naijiria naa ko rogbo fun awon mo.
Eyi to buru ninu re ni pe gbogbo ise ati owo ti awon eniyan naa ko jo ni won ko je ki won mu nnkankan ninu re ti won fi so won loko sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…