Home iroyin Babangida ati Afegbua fi oga Olopaa se yeye
iroyin - February 8, 2018

Babangida ati Afegbua fi oga Olopaa se yeye

Aare ologun tele ri ni orileede yii, ogagun Ibrahim Badamosi Babangida ni o pe olubaa-damoran lori iroyin, ogbeni Kassim Afegbua pe igba wo lo di odaran ti won n gbe si ori telifison pe won n wa?
Eyi ti o pa awon mejeeji lerin pe, bawo ni Ibrahim Idris to mofin se maa gbe iru nnkan bee si ori afefe pe awon n wa eniyan ti ajo olopaa ko tii ranse pe ki o wa, ti o wa ko eti ikun si won.
Afegbua yii ni iroyin gbee ni ose to koja pe Aare Mohammadu Buhari ko gbodo dije du ipo ni odun to n bo gege bi oga oun Ibrahim Babangida se salaye, iroyin miran gbee pe bee ko ni Babangida se soo. Afegbua lo pelu iyawo ati agbejoro re ni eyi ti o koko ba awon oniroyin soro ki o to lo ba awon olopaa ti won n waa. Abajade ipade naa ko tii han si araye gbo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…