Home iroyin Awon ojise Olorun lo fejo Fulani darandaran sun Buhari
iroyin - February 8, 2018

Awon ojise Olorun lo fejo Fulani darandaran sun Buhari

Awon ojise Olorun ni orileede yii ko ara won jo ni ojo kejo, osu yii lati je ki ijoba apapo mo bi inu awon se n baje to ti awon ba kaa ninu iwe iroyin pe awon Fulani darandaran pa eniyan.
Won ni bi ijoba Buhari se n gbiyanju to, won ni lati segun ija ojoojumo to n waye laarin awon Fulani darandaran ati awon agbe. Won je ki o ye ijoba apapo pe awon alaye to dibo fun won naa lo ye ki won se ijoba le lori, ko ye ko je oku.
Alagba Ignatus Kiagama lo ba awon oiroyin soro leyin ipade naa. Awon ojise Olorun yii koko ki Aare Buhari ati awon ti won jo n se ijoba ku akitiyan bi won se ko orileede yii kuro ninu oda ki won to wa salaye fun awon oniroyin pe ko si ise ni ilu bee si ni ko si ibale okan rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega Ọrẹ Òtítọ́jù “Ó dìgbà tí a bá dà…