Home Orisirisi Maradona digbo lu Buhari
Orisirisi - February 5, 2018

Maradona digbo lu Buhari

. Babangida ni Buhari ti d’agba ju eni to le se olori Naijiria
Leyin ose meji ti Oloye Olusegun Obasanjo laali Aare Muhammadu Buhari, olori ijoba ologun miiran tele, Ogagun Ibrahim Babangida, naa ti soko oro si Buhari.
O ni o ti dagba koja eni to le se ijoba daadaa.
O ni gbogbo ariwo ti ijoba APC pa pe awon fe mu iyipada ba Naijiria lo ja si pabo.
O ni olori ti Naijiria nilo bayii gbodo je olo elejetutu to mo nipa ogbon isejoba tode oni, to ni imo ero technology. Babangida ni kii se arugbo to je pe agbonrin esin lo fe maa je lobe.
Bakan naa, Babangida bu enu ate lu ijoba Buhari lori bi ko se gbe igbese gidi lori ipaniyan to n lo ni Naijiria, ati lori atunto ilu ati olopaa ipinle ti opo eniyan ni o dara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…