Home Orisirisi Idi ti n ko fi soro lori awon Fulani to n paayan – Pastor Adeboye
Orisirisi - February 3, 2018

Idi ti n ko fi soro lori awon Fulani to n paayan – Pastor Adeboye

Oludari Agba Lagbaaye fun ijo Redeemed Christian Church of God, Pastor E. A. Adeboye, ti se alaye idi ti oun ko fi maa soro lori awon Fulani darandaran to n pa awon eeyan nipakupa.
Opo eniyan lo ti n wo enu baba yii lati igba ti awon janduku naa ti n sose kaakiri awon ipinle.
Sugbon Baba Adeboye so lasiko ipago Holy Ghost Conference ti won se lopin ose yii pe oun ko kan soro taara funra oun ni, sugbon oun n soro.
O ni omo egbe Christian Association of Nigeria ati ti ajo Pentecostal ni oun. O ni loorekoore ni aare awon egbe yii n soro lori awon isele yii. O ni oun ti won ba si so, awon jo so o ni.
O wa gbadura ki Olorun fi oju awon asebi naa han.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega Ọrẹ Òtítọ́jù “Ó dìgbà tí a bá dà…