Home iroyin Obasanjo darapo mo egbe CNM
iroyin - February 1, 2018

Obasanjo darapo mo egbe CNM

Aare ana ni orileede Naijiria, Oloye Olusegun Obasanjo darapo mo egbe Coalition for Nigeria Movement (CNM) ni oni ojo Alamiisi, ojo kinni, osu keji odun yii.
Obasanjo ni oun ko darapo mo egbe yii lasan tabi nitori ote, sugbon nitori ife orileede yii. O ni gege bi ojo ori oun, se ipo ni oun n wa bayii ni abi okiki amo nitori ilosiwaju orileede yii.
Ara awon oludasile egbe naa ni gomina tele ri ni ipinle Eko ati Osun, Oloye Olagunsoye Oyinlola, Donald Duke ti ipinle Rivers ati awon eniyan jankan-jankan miran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…