Home iroyin E gbodo foju awon asebi Benue han – Saraki
iroyin - January 31, 2018

E gbodo foju awon asebi Benue han – Saraki

Gege bi olori ile igbimo asofin agba se salaye fun awon oniroyin, o ni ipaniyan to waye laarin awon Fulani darandaran ati awon eniyan ipinle Benue pelu agbegbe re gbodo loju kiakia.
O ni iru ise buruku to mu opo emi lo gbodo ni awon ti won maa fi jofin nigba ti awon olopaa ko ni ise miran ju ki won daabo bo gbogbo ara ilu lo.
Saraki ni Ibrahim Idris to je oga olopaa patapata ni orileede yii ti n pe ju lati foju awon asebi naa han. Ile igbimo asofin si paa lase pe iwadii naa gbodo te awon lowo-lowo ko to pe ju.
Ose meji pere ni won fun oga olopaa naa lati fi foju awon to seku pa awon eniyan naa han saraye.
Saraki ni aifoju awon asebi ipinle Benue han lo je ki iru nnkan buruku bee maa te siwaju ni awon ipinle to ku.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…