Home iroyin Customs gbagbara sii lowo ijoba apapo
iroyin - January 31, 2018

Customs gbagbara sii lowo ijoba apapo

Ijoba apapo ni awon ajo asobode ile wa (Customs) n gbiyanju nipa akitiyan won lato ma se je ki awon oja ti ijoba ko fe wo ilu yii. Ni eyi to je ki won gba oro won yewo nipa fifi kun awon anfaani ti won n je lati odo ijoba. Awon anfaani bii ile, owo ati awon ohun ija lati le fi koju awon onifayawo ti won n fi gbogbo igba ko oja buruku wole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…