Home iroyin Emi sun nibi ija Fulani darandaran ni Nasarawa
iroyin - January 29, 2018

Emi sun nibi ija Fulani darandaran ni Nasarawa

“Kaka ki ewe agbon de, pipele lo maa tun n pele sii”. Ijongbon awon Fulani darandaran ma tun mu emi eniyan meji lo nigba ti maluu metalelaadorin ba isele naa lo. Oro buruku tohun ti erin, ninu iroyin kayefi ni a ti maa n gbo pe maluu fara pa. Oro naa ti wa di iroyin ni Naijiria bayii. Nibi isele ipinle Nasarawa to sele lonii, maluu mejidinlogun lo fara pa.
Awon agbofinro ti te oko leti lo si ibi isele naa, won si ti petu sii, ki Eledua ba wa dawo aburu duro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…