Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ojo marun-un gbako ni Omotola fe fi se ojo ibi ogoji odun re
LÁGBO ÀRÍYÁ - January 25, 2018

Ojo marun-un gbako ni Omotola fe fi se ojo ibi ogoji odun re

Osere fiimu pataki, Omotola Jalaade-Ekehinde, yoo pe omo ogoji odun ninu osu keji to n bo yii.
Ko si mu ayeye ojo ibi naa ni kekere.
A gbo pe ojo marun-un gbako lo fe fi se e , pelu oniruuru eto.
Opo eniyan ro pe Omotola ti ju omo ogoji odun lo ni, boya nitori pe o ti di gbajumo tipe.
Ohun to sele ni pe kekere lo ti n se fiimu, bee o tun tete lo sile oko, to si ti n bimo tipe.
Pelu ojo ori re, o tumo si pe Funke Akindele, Mercy Aigbe ati Iyabo Ojo ju u lo, tori awon ti se ojo ibi 40 ti won.
Ki Olorun tubo lora emi re, ati ti gbogbo wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…