Home Orisirisi Yegede! Obasanjo di dokita
Orisirisi - January 21, 2018

Yegede! Obasanjo di dokita

oba
Aare Orile-ede yii tele, Oloye Olusegun Obasanjo, ti di oloye pupo bayii o. O ti gba oye imo ijinle dokita, ti Yoruba n pe ni Omowe.
Teletele, bi eniyan ba fe daruko re, a kii mo eyi to ye ka pe e – boya Ogagun ni o, tabi Oloye. Pelu Dokita to tun wa fi kun un, Obasanjo ti wa di Oyedipupo niyen.
Gbogbo oju lo wa lara re lojo Satide nigba to gba oye imo Ijinle naa, eyi to da leri imo nipa oro emi Theology, ni National Open University to wa ni Eko.
Pelu ohun ti a mo nipa Obasanjo, afaimo ko ma fee di ojogbon, iyen Professor, laipe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…