Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Sanchez fe so ile Arsenal di ahoro
ERÉ ÌDÁRAYÁ - January 21, 2018

Sanchez fe so ile Arsenal di ahoro

Onimo kan nipa ere boolu alafesegba, Ogbeni Ben Adedire, ti so pe adari egbe agbaboolu Arsenal, iyen Arsene Wenger, gbodo tete wa nnkan gbogi se ki egbe agbaboolu naa ma di eni eyin patapata.
O ni pelu bi Alesis Sanchez se n lo si Manchester United yii, ile Arsenal ti fe di ahoro patapata.
O ni, “Teletele, Sanchez lo fee je agbaboolu kan soso to gbadun ni Arsenal. Oun lo maa n mu ireti wa. Sugbon nigba to wa n lo yii, laasigbo airi ife eye gba yoo tuba ba Wenger sii.”
Egbe agbaboolu Barcelona naa ti fe gba alejo nla kan, iyen Phillip Conthino, eni ti yoo ropo Neymar to ti wa ni PSG bayii.
Opo eniyan lo gba pe ogo egbe naa yoo tubo yo sii.
Sugbon Adedire kilo pe adari egbe agbaboolu naa gbodo sora se. O ni o gbodo fi ogbon se e, tori ki o ma baa da egbe naa ru.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…