Home iroyin Naijiria ni lati sin eran ni ilana igbalode – Femi Falana
iroyin - January 20, 2018

Naijiria ni lati sin eran ni ilana igbalode – Femi Falana

Oro omugo lo maa n yato, bakan ni ti awon ologbon se maa n ri. Eyi difa fun imoran ti Agbejoro agba, Femi Falana gba orileede yii. O ni se bi won se n je eran naa ni won n sin eran ni ilu Oyinbo. O ni ko si igba ti eran di oju ona fun awon to n lo ibi ise won.
O gba ijoba apapo lamoran lati kan an nipa tabi soo dofin fun awon to n sin eraan pe, won ni lati sin-in ni ilana igbalode.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…