Home LÁGBO ÀRÍYÁ Remi Aluko soro lori oju to n dun un
LÁGBO ÀRÍYÁ - January 18, 2018

Remi Aluko soro lori oju to n dun un

Akorin fuji, Remi Aluko, ti opo eniyan mo si Aluko Remison, ti so idi ti oju fi n dun un, to je pe ko reran taara mo.
O ni arun kan ti o n je glaucoma, to maa n mu opo eniyan to ba ti le ni omo ogoji odun, lo mu oun.
Aluko ni ohun to hu arun naa jade ni bi eni kan se gba oun ni ese loju lojo tie de aiyede sele laarin awon.
O ni oun ti gbe arun naa lo fun ise abe ni orile-ede India, sugbon ko tii lo patapata

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…