Home Orisirisi Aki and Pawpaw ko oteeli nla
Orisirisi - January 18, 2018

Aki and Pawpaw ko oteeli nla

Okan lara awon osere Noliwuudu ti a n pe ni Aki and Pawpaw, iyen Osita Iheme, ti fihan pe oun kii se oninakuna tabi apa.
Gbogbo owo to ti ri ninu ere ti o ti kopa, ati awon ona miran ninu ise alariya, nnkan nla lo fi n se.
O ti pari oteeli nla kan ni ilu re ni Owerri, ni Ipinle Imo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…