Home iroyin Ìdàgbàsókè ìlú Adewoolu ló jẹ mí lógún – Dọja Adewoolu
iroyin - January 8, 2018

Ìdàgbàsókè ìlú Adewoolu ló jẹ mí lógún – Dọja Adewoolu

Ninu iwe itan fun igba akoko, lehin ti Oloogbe Alimi Adeniran Adewoolu, Sarumi Akoko ti gbogbo Egba, tii se baba Oloye Doja Adewoolu , Oloogbe Baale Jamiu Adepoju pelu awon miiran bee te Ilu Adewoolu do ni odun 1877 leyin ogun kiriji, gbogbo omo bibi Ilu Adewoolu nile loko, lehin odi labe akoso Baba wa Oloye Doja Adewoolu ( Otun ti Owu, Agoro ti Egba ati lowolowo bayii, pelu ase lati enu Olori Orileede wa Muhammadu Buhari , awon ni alaga gbogbogbo eto Ilera ti University Of BeninTeaching Hospital ) kora jopo si Ilu Adewoolu ni Ijoba Ibile Coker/ Ibogun LCDA ni Ojo Abameta, 30/12/2017 lati se ajoyo ati ikowojo fun idagbasoke ilu Adewoolu . (ADEWOOLU DAY ).
Baale ilu Adewoolu , Oloye Doja Adewoolu fi n to IROYIN OWURO leti wi pe “ Bi oko ba rokun, bo ba rosa, dandan ni ko fi abo fun Elebute” ati wi pe ile ni awon Yoruba n pe ni abo isinmi oko” Bi o ti le je pe awon ti n ko ipa idagbasoke ati riro awon odo ilu Adewoolu lagbara lati ibere pepe wa sugbon pelu ase lati enu Gomina Ibikunle Amosun fun idagbasoke ilu kereje .
Lara awon ti won fi ojo naa ye ilu Adewoolu si ni : Olu ti Ilu Ifo, Oba Samuel Ayerounwi 1, Olori ebi Ilu Adewoolu, Mama Hon. Justice Yetunde Adewoolu ( Aya Oloye Doja Adewoolu) Mama Ajihinrere Kemi Adetunji, Komisona fun ise asayan ni Ipinle Ogun Hon. Adeleke Adewoolu, Alaga Ijoba Ibile Coker/ Ibogun, Hon. Juwon Gbadebo, Igba keji Hon. Oguntade, awon councellor, gbogbo Baale Coker/Ibogun ati awon oninuure Ilu Adewoolu peju pese fun eto ikowojo idagbasoke Ilu Adewoolu lapapo!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…