Home Orisirisi VACANCY: Sefiu Alao n wa iyawo miran!
Orisirisi - January 7, 2018

VACANCY: Sefiu Alao n wa iyawo miran!

Akorin fuji pataki, Alhaji Sefiu Alao, ti fihan pe oun fe ni iyawo miran bayi o.
O ti to odun merin bayii ti Sefiu Alao ti mara duro, tori odun 2013 ni iyawo re, Iyaafi Nimotallahi, ti se alaisi.
Akorin ti alaje re n je Original Omo Oko so pe opo eniyan, to fi mo awon ebi oun ati ti iyawo oun, lo ti n gba oun niyanju pe ki oun fe iyawo miiran.
O ni loooto, opo obinrin to rewa ni oun maa n ba se alabapade, sugbon ko si eyi to fe waye labe asia okunrin ninu won.
O wa so pe bi oun ba ti ri eni to buyi kun aye oun, oun yoo gbe igbese to ye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…