Home iroyin El-Rufai lo ba Tunde Bakare lalejo ni soosi
iroyin - January 7, 2018

El-Rufai lo ba Tunde Bakare lalejo ni soosi

Soosi Latter Rain Assembly to wa ni ilu Eko gba alejo pataki kan ni Sunday oni, nigba ti Gomina Ipinle Kaduna, Mallam Nasir el-Rufai, be Oludari soosi naa, Pastor Tunde Bakare, lalejo.
Awon mejeeji di mo ara won gbagi, ti awon omo ijo si n wo won pelu iyanu nigba ti awon kan fi atewo si i.
Inu egbe CPC ni Tunde Bakare ati el-Rufai wa tele, nigba ti Bakare se igbakeji Aare Muhammadu Buhari ninu idijeti 2011.
Bi a ko ba gbagbe, ose to lo ni Bakare so pe Olorun ni ki oun gbe apoti ibo aare Naijiria leekan sii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…