Home Orisirisi Dele Momodu ni ki Buhari ma dabaa ati gbe apoti ibo ni 2019
Orisirisi - January 7, 2018

Dele Momodu ni ki Buhari ma dabaa ati gbe apoti ibo ni 2019

Okan lara awon ololufe Aare Muhammadu Buhari tele, Alagba Dele Momodu, ti sin in ni gbere ipako, to si so pe ki o ma dabaa ati gbe apoti ibo ni 2019.
O ni egbe APC ti kuna, to si je pe Buhari ti se iwon to le se.
O ni ijoba Buhari ko ni aseyoru gunmo kankan.
Ninu apileko kan, Momodu, eni to je oludasile magasin-in-ni Ovation, so pe opo awon ti Buhari ko rora, to ye ko maa ba sise idagbasoke, lo je pe onimadaru ni won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…